Iyawo – Jaymikee (Lyrics)

It’s jaymikee on the beat

E te eti, sile, Te e ba mo Eni to n kori

Is jaymikee on the beat

Iwe efesu ori ekarun ese ikejilelogun lati fa orin yi you

Oya

Iyawo jowo toju oko re

Bi ebi ba npa ro ewedu fun ati amala gbigbona

Bi ebi ba npa o ro efo fun ati iyan gbigbona

Bi ofun ba ngbe jowo bu omitutu si laya

Bi ofun ba ngbe o jowo bu omitutu si laya

Ma fun ni wahala fi i lokanbale

Ma fun ni wahala fi i lokanbale

Eje kin wi le kan si

Is jaymikee on the beat

END