Dide: Enoch Movie Sound track – Jaymikee (Lyrics)

Dide (Arise)
Emi Oluwa Jehova be Lara mi (The Spirit of the Lord is upon me)
Nitori ti oti fi Ami Ororo Yan mi (Cos he has anointed me)

Lati Was Fun awon otoshi (To Preach unto the lost ones)
Oti ran mi lati se awo tan oh (He has sent me to cleanse totally)

Gbogbo awon oni ro binuje okan (Those that are heart broken)
Ati gbogbo alayi ni ireti (to those that have lost hope)

Kede idasile fun awon igbekun (declare freedom to the captives)
ati sisi le tubu fun awon ounde (to set free the bound)
Didi (Arise) ×4

Kristeni Ologun (Christian Soldiers)

Kristeni mai ti wa sinmi o (Christian Seek yet reprose)
Beeni Angeli re wi (hear thy guardian angel say)

Ni arin ota lowa (ye are in the midst of foes)
Ma so ra (Watch and Pray) (×4)
Didi Arise

Ogun orun apadi (the host of hell)
ti a ko ri sugbon won ko ran won jo (that are gathered yet unseen)

won sho e (they are watching You) (×3)

Dide oh! (arise) (×5)
Kristeni Ologun (Christian Soldiers)